Yoruba ni airin jinna ni airi abuke ọkẹrẹ, bii eeyan ba rin jinna, yoo de ibi ti wọn ti n fi odo ibulẹ jẹun. Bẹẹ ni ọrọ ri pẹlu ilu kan, to jẹ kikida obinrin lo n gbe ibẹ amọ ti wọn ko gba ọ̀kunrin ...