Lanaa, ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ni Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu ṣe idasilẹ ileeṣẹ ti yoo maa ri sọrọ ohun ọsin lorileede yii pẹlu erongba pe idasilẹ ileeṣẹ ọhun yoo fopin si wahala to maa n fojoojumọ ṣẹlẹ ...
Imisi, ti orukọ abisọ rẹ n jẹ Opeyemi Ayanwale lo jawe olubori ninu eto Big Brother Naija Season 10, to si mu owo to ọgọtọ milọnu naira lọ si ile ati ọpọlọpọ ifẹ lati ọdọ awọn ololufẹ rẹ kaakiri ...
Some results have been hidden because they may be inaccessible to you
Show inaccessible results