Oṣere ati adẹrinpoṣonu, Damilola Adekoya, ti ọpọ mọ si Princess ti kede pe oun n wa ọkọ, oun si ti ṣẹtan lati ni ololufẹ. Princess lo sọ ọrọ naa ninu fidio kan to fi lede loju opo Instagram rẹ nibi to ...